text
stringlengths 21
135
| audio
audioduration (s) 2.83
17.8
| speaker_id
stringclasses 1
value | age_group
stringclasses 1
value | domain
stringclasses 1
value | gender
stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
nínú ọ̀rọ̀ tó kọ síbẹ̀ ló ti ní ẹ̀yin èèyàn mi
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
báyìí ni ọkùnrin onítìátà yìí ṣe sọ
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ẹ̀sùn táwọn [um] agbófinró ọ̀hún fi kàn wọ́n ni pé wọ́n ń ta egbòogi olóró èyí tó lòdì sófin [um] ilẹ̀ náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ìyẹn ló mú kí ọwọ̀ngọ̀gọ̀ ọjà ròkè lálá ròkè lálá báyìí a ò gbọ́ irú ẹ̀ rí nílẹ̀ yìí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ó ní wọn ò jí ohun èèlò ìdìbò kankan gbé
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lójú-ẹsẹ̀ lo ti figbe bọnu táwọn aráalé tí wọ́n ń gbé sí wàá wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀ sí i
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
alūkkóró ni àwọn máa tóó fojú rẹ balẹ̀-ẹjọ́ kó lè ṣàlàyé ohun tó rí tó fi gbé mọ́tò onímọ́tò lọ
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
[um] owó tí aláìsàn yẹn fẹ́ẹ́ [um] fi ṣàyẹ̀wò ní ṣùgbọ́n níṣẹ́ ni mo gbowó yẹn sá lọ
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
òfin òye jíjẹ́ la fara mọ́ ohun lá á sì máa bá lò
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
húṣáábù tó pẹyàwó ẹ̀ lẹ́jọ́ yìí fi kún un pé obìnrin náà ń ṣàgbèrè mọ́ òun lára
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
[um] báṣọ́run ìlú ọyọ́ àgbà-òye yusuf layinka tó jẹ́ olórí àwọn ọ̀yọ́mẹ́sì [um] ló léwájú àwọn olùpẹ̀jọ́ náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
tẹ̀gbọ́n-tàbúrò ni ọ̀làjúwọ́n àti lukumon tóun jẹ́ ẹni ogún ọdún péré
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gbé àsíá ńlá kan lọ́wọ́ bíi tàwọn boko háráàmù tàbí àwọn alákatakítí àjàgbàgbé àgbáyé
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
àgbègbè ìlọ́tí nílùú ijebu-òde nípínlẹ̀ ogun ni mò ń gbé
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
irọ́ bàǹtàbanta ló gbé kalẹ̀ pé wọ́n jí òun gbé tó sì ń béèrè owó ìtúsílẹ̀ lọ́wọ́ àwọnòbí rẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
àwọn aráalé náà ni wọ́n sáré lọ́ọ́ fọ̀rọ̀ ohun tó àwọn ọlọ́pàá ìbáfo létí táwọn yẹn fi wá síbẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lọ́sàn-án ọjọ́ ìṣẹ́gun túṣídéé ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún yìí ni arẹwà òṣèré yìí kéde ikú bàbà náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù keje ọdún 1986 ni wọ́n bí i
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mo lérò pé níbi pé níbi tí ìnáwó tó ga tún wà ní ọ̀rọ̀ mọ́tò wíwọ́
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ibrahim alágúnmu ìlọrin wọn ní ohun tí a ò bá fẹ́ kó bàjẹ́ ojú ni à á mú tọ́ ọ
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
orin àti amúlùúdùn ló ń gbé nàìjíríà lárugẹ báyìí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
adájọ́ kóòtù tí wọ́n fojú rẹ̀ bá sọ ọ́ sẹ́wọ̀n oṣù mẹ́rin pẹ̀lú iṣẹ́ àṣekára lọ́gbà ẹ̀wọ̀n
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ṣùgbọ́n ẹ̀yìn náà mọ̀ pé a ò tí ì ṣiṣẹ́ kankan lẹ́yìn tá a parí sinimá a tribe called judah
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
alūkó ni iléewòsàn ìjọba tó wà lágbègbè náà táwọn gbé olókàdá ọ̀hún lọ ló ti ń gba ìtọ́jú báyìí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mi ò mọ̀ bóyá ó ti gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀ sí mi yìí o
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mọ́ńsóná saka olùfúngẹ́ ọmọ akíndélé ẹni tí inú ọlọ́run dùn sí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
kì í sì í ṣe irú èyí tí yóò jẹ́ kéèyàn jẹ́ kéèyàn dèrò ọsibítù látàrí àìrí oúnjẹ gidi jẹ
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
amúlùúdùn ló ló ń mú owó wọlé o [um]
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ibẹ̀ ṣáá ni mo ti bá a láṣepọ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ó sáré lọ́ọ́ dúró sáàrin òde èmi náà sì dọ́gbọ́n sá pamọ́ sínú balùwẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lọ síbẹ̀ lọ sọ́dọ̀ wọn dá wọn lóhùn ohun tí wọ́n bá bi ẹ́
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ẹ̀yin àtàwọn ọmọ yín àti gbogbo nǹkan-ìní yín àti ohun tó kàn yín ni ọlọ́run ti dáàbò bò
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
àwọn aráàlú ní eré àsápajúdé àti títí tí kò dáa ló ṣokùnfà ìṣẹ̀lẹ̀ láabi ọ̀hún
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ọmọ ìyá mi ẹ́ [um] gbàgbé òsì ebi ń pa àwọn [um] èèyàn
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
kí ọlọ́run túbọ̀ máa ṣọ́ wa kí ó sì máa darí ìgbésẹ̀ wa
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ní kété tó dénú àkáǹtì rẹ̀ lòun náà fi ṣọwọ́ sí oríṣiríṣiì iléeṣẹ́ àtàwọn èèyàn
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ó rọ àwọn èèyàn láti fọwọ́sowọ́pọ̀ láti mú kí ayé kò dáa fún gbogbo wa
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ẹnikẹ́ni kò tí ì fojú kàn wọ́n láti ọjọ́ furuufé
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mi ò sí pẹ̀lú ọpọlọ mi ní gbogbo àkókò yẹn mo ti yọ̀ pẹ̀lú nǹkan tí mo mú
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
wọ́n padà ṣekú pa ọ̀kan nínú wọn láàárọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ ìṣègùn túṣídéé ọ̀sẹ̀ yìí tí wọ́n sì tún dáná sunlẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lẹ́yìn tí wọ́n fìyà jẹ obìnrin yìí tán ni wọ́n tún wọ òbítíbitì owó kúrò nínú àpò báńkì rẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ìsẹ̀lẹ̀ ọ̀hún wáyé [um] lágbègbè garin-alkálì lẹ́gbẹ̀ẹ́ ìlú gashọ́n níjọba ìbílẹ̀ bàdé [um] nípínlẹ̀ yobe
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ó ṣàlàyé pé àwọn ọlọ́pàá ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ọ̀rọ̀ náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
léyìí tó kan àwọn ọlọ́pàá àti ológun ilé wa
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ó ní mi ò bá ẹnìkankan sọ̀rọ̀ náà rí mi [um] ò mọ ibi tí ìbátan mi ti gbọ́rọ̀ [um] náà rárá
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ẹ̀wọ̀n oṣù mẹ́fà ni adájọ́ ilé-ẹjọ́ kan nílùú èkó sọ bob risky sí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ìrìnàjò tó kún fún oríṣiríṣiì nǹkan ni ìrìnàjò àwa pẹ̀lú wọn nígbà tí wọ́n wà láyé
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ọlọ́ìyá ni láìpẹ́ làwọn yóò fojú àwọn afurasí náà balẹ̀-ẹjọ́
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
tẹ́ ẹ bá gbé mi ẹ máa gbé mi jù sílé ẹ tún máa tẹ ọwọ́ sí mi ni
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èèyàn wa tí wọ́n ń gba ojú ọ̀nà yìí máa ṣe pẹ̀lẹ́
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lára àwọn èèyàn yìí tí wọ́n gbajúmọ̀ lórí ìkànnì tiktok ni olóríẹbí musicroduzione2 operny bee àti wetsuko
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
n ní ọkùnrin tó bá aláṣẹwọ́ sún ọ̀hún ná lọ́ọ́ fọ̀rọ̀ náà tó wọn létí ní tẹ̀sán ọlọ́pàá àgbègbè náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ọ̀pọ̀ àwọn ilé ṣọ́ọ̀bù tó wà ládùúgbò ọ̀hún ni wọ́n fara gbá nínú ìṣẹ̀lẹ̀ náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
[um] wọ́n máa ní kí n máa lọọlẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lórí èrò ayélujára ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lójú táwọn èèyàn fi wo ohun tí bob risky ṣe yìí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ fún mi fúnkẹ́ akíndélé ló ti máa ń fún un lọ́wọ́ oògùn yẹn lóṣooṣù
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lẹ́yìn tí wọ́n bá sanwó yìí tán ni wọ́n máa fi [?] rìsíìtì wọn ránṣẹ́ sí ìímeèlì iléeṣẹ́ náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
aláròye gbọ́ pé ó ti pẹ́ tí afurasí ọ̀daràn ohun tí ń ṣiṣẹ́ láabi ọ̀hún
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ṣe ló ká àwọn òrùlé ilé àtàwọn ṣọ́ọ̀bù kan lọ pátápátá nígbà tó fi àwọn mí-ín sílẹ̀ láàbò
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ọ̀ràn yìí ni wọ́n lọ la ìjìyà lọ lábẹ́ òfin ọdún 2000 èyí tó ṣe ìwà ọ̀daràn léèwọ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
[um] gbogbo egbòogi olóró tó yá tó sì bí mọ́ èébì yìí jẹ́ gíráàmù ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún dín díẹ̀ láàrin ọjọ́ [um] mẹ́rin
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ìgbà tí wọ́n pa ọmọ mi tán tí wọ́n tún fẹ́ẹ́ pa liam wọ́n tún fẹ́ẹ́ pa mí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ gbogbo wa la fẹ́ràn àlàáfíà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mo ń gbé ní àdúgbò first pípilẹ̀ iṣẹ́ aṣọ òkìkí títa ni mò ń ṣe mò ń kiri ni
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
tẹ́ ò bá gbàgbé nínú oṣù kẹsàn-án ọdún 2023 ni olóògbé ni olóògbé mohbad dágbére fáyé lẹ́ni ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
[um] lójijì ni àwọn fúlàní márú-ún kan [um] déédé wọlé pẹ̀lú ìbọn àti àwọn òun ìjà olóró mìíràn
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
iṣẹ́ oko ríro ni mò ń ṣe mo dé tún ń ṣe alágbàṣe fáwọn àgbẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
awakọ̀ àwọn olóògbé nígbà kan rí ni ni wọ́n pe marcus
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
o ò nílò láti ṣèdíwọ́ fáwọn tó fẹ́ẹ́ mú ẹ tàbí ṣe é bákan
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
[um] ọgbà ẹ̀wọ̀n kì í ṣe ibi téèyàn gbọ́dọ̀ dúró sí fún ọjọ́ [um] kan péré
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ó lóun kábàámọ̀ pé ikú obìnrin náà tọwọ́ òun [um] wà nítorí ọ̀rọ̀ fóònù [um] tó fa fá-ń-fà láàrin àwọn
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lójú-ẹsẹ̀ lèèyàn kàn sì ti jáde láyé tí láyé tí èèyàn méjì sì tún fara pa
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé láàárọ̀ kùtùkùtù ọjọ́ kùtùkùtù ọjọ́ ajé monde ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kẹrin ọdún yìí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
tòsìn ni wọ́n lọ ń gbé ojúlé kejìdínláàádọ́sàn-án ọ̀nà nantes ní ìjọkọ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ẹ jẹ́ kí n fún yín ní àpẹẹrẹ
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
wọ́n ti tún fẹ́ẹ́ dí ọ̀nà ibi tí a ti ń jẹ
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
èyí [um] kò ṣẹ̀yìn bí ọmọbìnrin náà ṣe pàdánù bàbá tó bí i [um] lọ́mọ lẹ́ni ọgọ́rin ọdún
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
iléeṣẹ́ tó ń rí sọ́rọ̀ àwọn obìnrin nípínlẹ̀ náà ni wọ́n lọ́ọ́ fi páńpẹ́ òfin gbé ọkùnrin yìí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ṣùgbọ́n ọ̀nà abubakar ti jìn ní tiẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
lẹ́yìn náà ló ṣẹ̀ṣẹ̀ wáá yìnbọn pa ara rẹ̀ mọ́nú mọ́tò tó gbé lọ sọ́dọ̀ àwọn àna rẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
tẹ́ ẹ bá rí [um] mi tí mo dá owó àwọn alátìlẹyìn mi ni mò [um] ń fún
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mo wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú àdúrà idris okinye
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
gẹ́gẹ́ bá a ṣe gbọ́ kò tíì sẹ́ni tó mọ pàtó ohun tó ṣokùnfà ikú òjijì fún òṣèré náà
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
bí wọ́n wọ́n ṣe kojú ara wọn ni wọ́n ti yìnbọn pa ẹnì kan lára wọn
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
níṣẹ́ ni iná elétíríìkì gbé e tó sì kú pátápátá
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
bẹ́ẹ̀ owó tí wọ́n ń ná fáwọn yìí ló máa ń jẹ́ kí orí àwọn wú láti kọrin
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mo kàn fi àtẹ̀jíṣẹ́ ṣọwọ́ sí jíde nì ṣe é mọ̀ pé a dá jenifas mystery dúró fúngbà kan ná
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ó wà lábẹ́ òrùlé mi àmọ́ ojú rẹ̀ ṣì wà níta
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ń láwọn wọ́dà náà bá ń ti ẹ̀bi ọ̀rọ̀ ọ̀hún síra wọn
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
àwọn aráàlú gbìyànjú láti paná ọ̀hún ṣùgbọ́n wọn kò ní irinṣẹ́ tó tó láti kojú rẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
fún àlàyé kíkún ẹ lè pẹ́ sórí àwọn ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ wọ̀nyí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ní báyìí wọ́n tún ti fi kún ọwọ́ iná eléńtíríìkì
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ọ̀rọ̀ ọwọ́ngọyọ epo bẹntiróòlù tó wà níta báyìí ló mú káwọn aráàlú lọ́ọ́ tó sílẹ̀-èpò tó wà lágbègbè ọbalẹ́ńdẹ́
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ọmọnúà jẹ́ alága rẹ̀ fi ṣọwọ́ sílẹ̀ẹ́gbìmọ̀ asòfin náà lọ́jọ́ furuufée tó kọjá
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
àwọn aráàlú kan ni wọ́n rí òkú géńdé náà níbi tí iná ẹlẹ́tíríìkì pa á sí
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
ẹ jẹ́ kí [um] n sọ bí a ṣe fẹnu [um] kò lórí iye yìí sí wẹ́wẹ́ fún yín
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
èèyàn mẹ́sàn-án ni wọ́n yìnbọn pa lábúlé maritza-mushu nígbà tí wọ́n pa mẹ́jọ lábúlé kọ́pánlẹ̀
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
owó ló ń ṣe kóríyá fáwa olórin
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
mi [um] ò mọ ohun tí mo rà nígbà ààrẹ [um] tí wọ́n fi lè pa irú irọ́ bẹ́ẹ̀ mọ́ mi
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
|
pẹ̀lú ìbànújẹ́ tó ga èmi ní ẹnilọ́ ajáò
|
YECT1F19
|
15-29
|
EV
|
female
|
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 4