text
stringlengths 21
130
| audio
audioduration (s) 2.38
15.8
| speaker_id
stringclasses 1
value | age_group
stringclasses 1
value | domain
stringclasses 1
value | gender
stringclasses 1
value |
|---|---|---|---|---|---|
mo wọ ilé kejì wá mi ò rí wọn mo bẹrẹ sí í sunkún
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
quadri yìí kan náà ló mú àwọn ọlọpàá délé àwọn olùdaré yẹmísì àti ọkọ rẹ ọgbẹni olùdaré ọlámilekan
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ẹnu lílù ọhún ló wà tí bàbá náà fi dákẹ mọ ọn lọwọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
títí di òní yìí sí ni iléeṣẹ jẹnifà ṣì wà digbí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ṣé àwọn èèyàn kan kọ ni wọn ń tọ ọmọ aláìníyàá àti bàbá ni
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lẹyìn tí wọn jáde síta padà ni lala fúnra ẹ fẹsẹ ràjò pẹlú mercy aigbe àti jayé kùtì
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ohun àlùmọọnì tó wà nípínlẹ kóówá wa ló yẹ ká máa lò láti fi ṣètò ìdàgbàsókè fúnra wa
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ẹ jọọ kí ló kàn mí pẹlú gbogbo ìyẹn
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
bẹẹ ló rọ àwọn méjèèjì láti sinmi ìjà kí wọn sì gba àlàáfíà [?] láàyè
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
fatia ni pẹlú ọkàn tó wúwo ò bà mí lọkàn jẹ láti sọ pé ó dàárò fún bàbá mi ọwọn
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó ní lójúẹsẹ làwọn ọmọkùnrin mẹta tó wà nínú ọkọ akóyọyọ náà jáde láàyè nígbà tí ẹnì kan farapa yánnayànna
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
kò pẹ rárá tí wọn jẹ oúnjẹ ọhún tán ni inú bẹrẹ sí í run gbogbo wọn
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
gokwat sàlàyé pé ìwà tó lòdì tó sì níjìyà lábẹ òfin ìwà ọdaràn ti ìpínlẹ plateau ni ọmọkùnrin náà hù
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọrọ yìí ló di wàhálà tó sì di pé lẹkàn lu obìnrin náà tó tún gé e jẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
nínú ìpínlẹ kan náà tí ọpọlọpọ àwọn òṣìṣẹ ìjọba ń tiraka láti gbé ilẹ ayé
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
alūkó ni iléewòsàn ìjọba tó wà lágbègbè náà táwọn gbé olókàdá ọhún lọ ló ti ń gba ìtọjú báyìí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
bákan náà ni alūkkoro fún ẹgbẹ nnl ogbeni benson upah ti fèsì lórí ọrọ táwọn gómìnà sọ ọhún
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ìdàrúdàpọ wáyé látàrí àìnísùúrù àwọn èèyàn láti tẹlé òfin tí wọn là kalẹ fún títa ìrẹsì ọhún
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lójúẹsẹ lèèyàn kàn sì ti jáde láyé tí láyé tí èèyàn méjì sì tún fara pa
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lásìkò tó ń pọn omi ọhún lọwọ kò sí iná lágbègbè náà
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
alūkkóró àjọ sífù fífẹǹsì nípìnlẹ ọsùn kẹhìndẹ adélèké fìdí ìṣẹlẹ náà múlẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
mo gbà á ládùúrà pé o ò ní ṣubú láéláé
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lẹyìn èyí ló tóó fi tóó fi í sílẹ tó sì sá kúrò níbẹ káwọn èèyàn tóó dé
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
kò [um] jọ pé ó lóyún o kò tiẹ lóyún
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó ní àwọn tí taari ọkùnrin náà lọ sí iléeṣẹ ọtẹlẹmúyẹ fún ìtẹsíwájú ìwádìí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
o ní ìwádìí kíkún ti bẹrẹ [?] lórí ẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ìwà ìyá ni adájọ hù gẹgẹ bí èèyàn ṣe ń bá ọmọ ẹni wí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lọjọ etí furcabee ọhún ni ìròyìn ikú ọkùnrin kan kọkọ gba orí ẹrọ ayélujára kan
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lẹyìn tó pa tó pa á tán ló tún jí ọkadà rẹ gbé sá lọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
gbogbo fọọmù tí olùwáṣẹ tẹ jáde ni alákòóso ètò ìbúra nílẹẹjọ tó kúnjú tó kúnjú òṣùnwọn gbọdọ lù lọńtẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
alūkkóró ni láìpẹ yìí làwọn máa bá a ṣẹjọ lórí ìwà tó hù
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
èèyàn méje ló wà [um] nínú ọkọ ayọkẹlẹ ohun obìnrin àgbàlagbà mẹrin ọkùnrin àgbàlagbà kan ọmọdékùnrin kan àti ọmọdébìnrin kan [um]
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
láti lè mọ ti gírí anaphylococcus àfi kí wọn gba ẹjẹ irú ẹni bẹẹ lójúẹsẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
orúkọ àwọn tí wọn jí gbé [um] ọhún ni ṣèyífúnmi ọlàdàpọ àti abiola [um] olùbọọyẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
internationl abdullahi ibrahim jẹ ọmọ bíbí agboolé aláàjì ibrahim nílùú saki níjọba ìbílẹ saki nípínlẹ ọyọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
akọwé ìjọba àpapọ seneto george akume ló fi ṣe olórí ìgbìmọ náà
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ṣùgbọn agbófinró yìí fi àjùlọ hàn wọn ọwọ tẹ watab ṣùgbọn àwọn ẹgbẹ rẹ yòókù ráàyè sá lọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
wíwá yín yóò ràn ràn wá lọwọ lórí ìdájọ òdodo tí à ń fẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
àwọn kọọkan tí kò kú wà níléemọsán ìjọba orílẹèdè náà báyìí tí wọn ń gba ìtọjú lọwọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
láti [um] ìkọkọ ni màmá mi ti gbé mi kúrò [um] lọdọ bàbá mi tí wọn kọra wọn sílẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
nǹkan ayọ kọ ni í wọn nílé gbogbo wa o
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lórí èrò ayélujára ọtọọtọ lójú táwọn èèyàn fi wo ohun tí bob risky ṣe yìí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
a lè ṣe é a ò sì ríbi ṣe é
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó ní lojoruu wesidee ọjọ kẹrìnlélógún oṣù kẹrin yìí ni ọjà náà yóò jẹ ṣíṣí padà
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
bákan náà ni fúnkẹ sọrọ síwájú pé ẹẹkan kan ni dbanj jẹ kì í kàn ṣe olórin kan ṣáá
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó dùn mí pé obìnrin yẹn kú
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó ní àwọn máa tóó fojú àwọn ọdaràn ọhún balẹẹjọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
níbẹ làwọn àràádúgbò [um] tí lọọ pé ọlọpàá wàá mú èmi àti [um] dádì mi wọn láwá là pa á
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
torí àwa ò tiẹ tí ì gba ọgọta gba ọgọta ẹgbẹrún tí wọn ń pariwo ẹ yìí wọlé o
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọkanòjọkan eré ni òṣèré náà ti kópa
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
a ní láti ṣèwádìí nípa iléeṣẹ yìí dáadáa
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
alūkkóró [um] ni ìbọn ogún làwọn èèyàn náà ti ta síta [um] fáwọn oníbàárà wọn gbogbo
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
èyí ló mú kó sọ ọ sẹwọn ọdún mẹrìnlá gbáko pẹlú gbáko pẹlú iṣẹ àṣekára lọgbà ẹwọn kirikiri nílùú èkó
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
alūkkóró ni àwọn ń ṣèwádì nípa rẹ lọwọ táwọn ṣì máa wọ ọ lọ sí kóòtù táwọn bá ti parí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó ní ọrẹ òun kò sọ fóun àtàwọn tí àwọn jọ jókòó pọ tó fi gba odò lọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
àwọn aládùúgbò ni ọkùnrin náà pé pé kí wọn bá òun wọ bàbá àti màmá òun nínú ilé
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
gẹgẹ bí ọba ákànbí ṣe sọ odidi òrùlé kíláàsì mẹwàá ní iléèwé st
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
èyí ni l picc pé ní páńpẹ tí iyábọ àtàwọn tiẹ dé kalẹ fóun láti lè ba òun lórúkọ jẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
mo ń gbé ní àdúgbò first pípilẹ iṣẹ aṣọ òkìkí títa ni mò ń ṣe mò ń kiri ni
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ògúngbẹmí sọ síwájú pé iléèwòsàn uniosangah ni wọn gbé ẹni tó fara pa náà lọ fún ìtọjú
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọpọ àwọn olólùfẹ òṣèré yìí àtàwọn ẹlẹgbẹ rẹ nídìí iṣẹ tíátà ni wọn ti ń ṣọfọ òṣèré ńlá yìí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
oníkálukú kan ń wa ẹkún mu bíi gàárì ni [um] kò sì sẹni tó ṣe [um] ẹnì kan ní pẹlẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọrọ àwọn ọmọ tí wọn kò rí iléèwé lò ò lè jẹ ìtẹwọgbà
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
adùnjọlá ní [um] ọsibítù òun ni wọn gbé ọkùnrin [um] náà dìgbàdìgbà wá
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
mo kàn rọra gbé e lórí ẹsẹ mi lásán báyìí ní títí tí mo fi dá nǹkan sí i lára
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
pẹlú gbogbo [um] ìkìlọ tá a ti ṣe fáwọn [um] iléeṣẹ yìí wọn kò torí ẹ má tàpá sí àṣẹ láṣèbè
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó ní lápapọ ẹgbẹrún mẹta dín díẹ ní àwọn tí wọn ti jàǹfààní ètò náà
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọmọ ẹgbẹ òsèlú all progressives congress ní peller látilẹ orúkọ ẹgbẹ ọhún ló fi dìbò wọlé ìgbìmọ asojúṣòfin
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọlọpàá tí kò wọṣọ ló fẹẹ yìnbọn mọ tí wọn fi mú un
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọláìyá ni lẹyìn ẹkúnrẹrẹ ìwádìí làwọn yóò fojú àfurasí náà balẹẹjọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
mo gbàdúrà pé ọlọrun ọba àá fọpo rọpò fún yín bẹẹ bá lè ṣe bẹẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
méjì lára wọn wọn lọwọ tẹ nígbà táwọn yòókù wọn ráàyè sá lọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ìgbésí ayé tó nítumọ ni kábíésì gbé láyé
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
[um] ó ti ṣe díẹ tí àìsàn ti ń bá òṣèré [?] náà fínra tó sì ń pààrà [um] iléèwọsàn
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó sì gbàjọba nímọràn láti sọ àwọn àmọtẹkùn tí wọn [um] wà lẹnu iṣẹ lọwọlọwọ báyìí di ọlọpàá ìpínlẹ [um]
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
agbosọgbànu ni ikú igbákejì kọmíkànńdà ọlọpàá èkó ọhún sí gbogbo àwọn tó gbọ ọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lásìkò náà ni ọmọkùnrin yìí lagi mọ ìyá mayowa lórí ó fipá bá a láṣẹpọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
èyí ló mú kí wọn [um] túbọ fimú fínlẹ tọwọ [um] sí bá yakubu
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
kò ju ìṣẹjú [um] díẹ lẹyìn náà ni wọn sọ fún mi pé obìnrin yẹn [um] ti kú
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
oríṣìí ẹsùn méjì ni àgbéfọba olúṣọlá sọnẹyẹ tó jẹ olùpẹjọ fi kan olágbẹdẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
àwọn ọlọpàá bi í léèrè bí àwọn fọtò náà ṣe jẹ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
a ti gbé òkú àwọn mẹtẹẹta ọhún lọ sí mọṣúárì iléèwésàn kan tó wà lágbègbè sagamu nípínlẹ ogun
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
lòsùn oyetola di olùdíje fún ẹgbẹ́ apc àwọn tọ́p fìdí-rẹmi
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
wọn lọọ fọwọ òfin mú òun náà nílé rẹ tó wà lọjọlẹ kẹta ilélábáyò close lágbègbè ajásà nílùú èkó
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ṣùgbọn nígbà tó yá ni atòlógbè ní kí ọpẹ gbé igi lọ síbi tí wọn ti fẹẹ dáná
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ibrahim alágúnmu ìlọrin wọn ní ohun tí a ò bá fẹ kó bàjẹ ojú ni à á mú tọ ọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
a ṣì máa fọwọsowọpọ pẹlú yín lórí eléyìí dáadáa
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọgá ọlọpàá ni àwọn yóò fojú àfurasí balẹ [um] ẹjọ tí ìwádìí bá ti [um] parí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ayédèrú ọtí líle àti wáìnì ni wọn máa ń ṣe ta fáwọn aráàlú kọwọ tóo tẹ wọn
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
a ó ṣá àwọn ṣọọṣì tá a bá máa fún lọwọ mú ni
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
wọ́n sì ń wá ìyàwó ilé tó pa ọkọ ẹ̀ pẹ̀lú pẹ̀lú omi gbígbóná lápbẹ́ọ̀kúta
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ẹnu ìjà náà ni wọn wà lọwọ tí olóògbé apele fi ṣubú lulẹ gbalaja tó sì ń pọkàkà ikú
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ọgá ọlọpàá ni àwọn máa tóó fojú gbogbo wọn balẹẹjọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
àdúgbò gidi ni ẹ wá ààyè sí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
kábíésì ganan là ganan là bá máa pè ní gbọbániyí
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
oyetola adeoti àti [um] lásùn fara hàn níwájú ìgbìmọ̀ tí yóò ṣètò ìdìbò abẹ́lé [um] lọ́sùn
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ó jẹ ọkan nínú àwọn aláwàdà tí kì í ṣe wàhálà rárá kó tóó dẹrìnín pààyàn
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ibrahim alágúnmu ìlọrin àsè òótọ lọwẹ yorùbá tó ní ìyàn ogún ọdún á máa jó ní lọwọ fẹlẹfẹlì
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
olóògbé private alhaji isah jẹ ọmọ bíbí aláàjì [um] isah nílùú gadaka níjọba ìbílẹ [um] fíkà nípìnlẹ yobe
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
|
ẹ ní kó lọá wá ẹrí jọ
|
YECT2M27
|
30-45
|
EV
|
male
|
End of preview. Expand
in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 3